2. A. Ọba 19:12 YCE

12 Oriṣa awọn orilẹ-ède ha gbà awọn ti awọn baba mi ti parun; bi Gosani, ati Harani, ati Resefu, ati awọn ọmọ Edeni ti o wà ni Telassari?

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 19

Wo 2. A. Ọba 19:12 ni o tọ