2. A. Ọba 2:24 YCE

24 O si yipada, o si wò wọn, o si fi wọn bú li orukọ Oluwa. Abo-beari meji si jade lati inu igbó wá, nwọn si fà mejilelogoji ya ninu wọn.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 2

Wo 2. A. Ọba 2:24 ni o tọ