2. A. Ọba 22:2 YCE

2 On si ṣe eyiti o tọ́ li oju Oluwa o si rìn li ọ̀na Dafidi baba rẹ̀ gbogbo, kò si yipada si apa ọ̀tún tabi si apa òsi.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 22

Wo 2. A. Ọba 22:2 ni o tọ