2. A. Ọba 23:26 YCE

26 Ṣugbọn Oluwa kò yipada kuro ninu mimuná ibinu nla rẹ̀, eyiti ibinu rẹ̀ fi ràn si Juda, nitori gbogbo imunibinu ti Manasse ti fi mu u binu.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 23

Wo 2. A. Ọba 23:26 ni o tọ