2. A. Ọba 23:34 YCE

34 Farao-Neko si fi Eliakimu ọmọ Josiah jẹ ọba ni ipò Josiah baba rẹ̀, o si pa orukọ rẹ̀ dà si Jehoiakimu, o si mu Jehoahasi kuro; on si wá si Egipti, o si kú nibẹ.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 23

Wo 2. A. Ọba 23:34 ni o tọ