2. A. Ọba 24:5 YCE

5 Ati iyokù iṣe Jehoiakimu, ati gbogbo eyiti o ṣe, a kò ha kọ wọn sinu iwe ọ̀rọ ọjọ awọn ọba Juda?

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 24

Wo 2. A. Ọba 24:5 ni o tọ