2. A. Ọba 25:21 YCE

21 Ọba Babeli si kọlù wọn, o si pa wọn ni Ribla ni ilẹ Hamati. Bẹ̃li a mu Juda kuro ni ilẹ rẹ̀.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 25

Wo 2. A. Ọba 25:21 ni o tọ