2. A. Ọba 25:22 YCE

22 Ati awọn enia ti o kù ni ilẹ Juda, ti Nebukadnessari ọba Babeli fi silẹ, ani, o fi Gedaliah ọmọ Ahikamu, ọmọ Ṣafani, jẹ bãlẹ wọn.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 25

Wo 2. A. Ọba 25:22 ni o tọ