2. A. Ọba 5:17 YCE

17 Naamani si wipe, Njẹ, emi bẹ̀ ọ, a kì yio ha fi erupẹ ẹrù ibàka meji fun iranṣẹ rẹ? nitori lati oni lọ iranṣẹ rẹ kì yio rubọ sisun, bẹ̃ni kì yio rubọ si awọn ọlọrun miran, bikòṣe si Oluwa.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 5

Wo 2. A. Ọba 5:17 ni o tọ