Neh 5:16 YCE

16 Mo si mba iṣẹ odi yi lọ pẹlu, awa kò si rà oko kan: gbogbo awọn ọmọkunrin mi li o si gbajọ sibẹ si iṣẹ na.

Ka pipe ipin Neh 5

Wo Neh 5:16 ni o tọ