Sek 8:2 YCE

2 Bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi; owu nlanla ni mo jẹ fun Sioni, ikannu nlanla ni mo fi jowu fun u.

Ka pipe ipin Sek 8

Wo Sek 8:2 ni o tọ