Sek 8:22 YCE

22 Nitõtọ ọ̀pọlọpọ enia, ati awọn alagbara orilẹ-ède yio wá lati wá Oluwa awọn ọmọ-ogun ni Jerusalemu; ati lati gbadura niwaju Oluwa.

Ka pipe ipin Sek 8

Wo Sek 8:22 ni o tọ