Iṣe Apo 10:41 YCE

41 Kì iṣe fun gbogbo enia, bikoṣe fun awọn ẹlẹri ti a ti ọwọ Ọlọrun yàn tẹlẹ, fun awa, ti a ba a jẹ, ti a si ba a mu lẹhin igbati o jinde kuro ninu okú.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 10

Wo Iṣe Apo 10:41 ni o tọ