Iṣe Apo 10:42 YCE

42 O si paṣẹ fun wa lati wasu fun awọn enia, ati lati jẹri pe, on li a ti ọwọ Ọlọrun yàn ṣe Onidajọ ãye on okú.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 10

Wo Iṣe Apo 10:42 ni o tọ