19 Awọn Ju kan si ti Antioku ati Ikonioni wá, nigbati nwọn yi awọn enia li ọkàn pada, nwọn si sọ Paulu li okuta, nwọn wọ́ ọ jade kuro ni ilu na, nwọn ṣebi o kú.
Ka pipe ipin Iṣe Apo 14
Wo Iṣe Apo 14:19 ni o tọ