20 Ṣugbọn nigbati awọn ọmọ-ẹhin duro tì i yiká, o dide, o si wọ̀ ilu na lọ: ni ijọ keji o ba Barnaba lọ si Derbe.
Ka pipe ipin Iṣe Apo 14
Wo Iṣe Apo 14:20 ni o tọ