Iṣe Apo 15:4 YCE

4 Nigbati nwọn si de Jerusalemu ijọ ati awọn aposteli ati awọn àgbagbà tẹwọgba wọn, nwọn si ròhin ohun gbogbo ti Ọlọrun ti fi wọn ṣe.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 15

Wo Iṣe Apo 15:4 ni o tọ