Iṣe Apo 15:5 YCE

5 Ṣugbọn awọn kan ti ẹya awọn Farisi ti nwọn gbagbọ́ dide, nwọn nwipe, a ni lati kọ wọn ni ilà, ati lati paṣẹ fun wọn pe ki nwọn ki o mã pa ofin Mose mọ́.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 15

Wo Iṣe Apo 15:5 ni o tọ