Iṣe Apo 20:6 YCE

6 Awa si ṣikọ̀ lati Filippi wá lẹhin ọjọ aiwukara, a si de ọdọ wọn ni Troasi ni ijọ karun; nibiti awa gbé duro ni ijọ meje.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 20

Wo Iṣe Apo 20:6 ni o tọ