Iṣe Apo 20:7 YCE

7 Ati ni ọjọ ikini ọ̀sẹ nigbati awọn ọmọ-ẹhin pejọ lati bù akara, Paulu si wasu fun wọn, o mura ati lọ ni ijọ keji: o si fà ọ̀rọ rẹ̀ gùn titi di arin ọganjọ.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 20

Wo Iṣe Apo 20:7 ni o tọ