Iṣe Apo 23:17 YCE

17 Paulu si pè ọkan ninu awọn balogun ọrún sọdọ rẹ̀, o ni, Mu ọmọkunrin yi tọ̀ olori-ogun lọ: nitori o ni nkan lati sọ fun u.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 23

Wo Iṣe Apo 23:17 ni o tọ