Iṣe Apo 26:10 YCE

10 Eyi ni mo si ṣe ni Jerusalemu: awọn pipọ ninu awọn enia mimọ́ ni mo há mọ́ inu tubu, nigbati mo ti gbà aṣẹ lọdọ awọn olori alufa; nigbati nwọn si npa wọn, mo li ohùn si i.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 26

Wo Iṣe Apo 26:10 ni o tọ