Iṣe Apo 26:11 YCE

11 Nigbapipọ ni mo ṣẹ́ wọn niṣẹ ninu gbogbo sinagogu, mo ndù u lati mu wọn sọ ọrọ-odi; nigbati mo ṣoro si wọn gidigidi, mo ṣe inunibini si wọn de àjeji ilu.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 26

Wo Iṣe Apo 26:11 ni o tọ