Iṣe Apo 28:2 YCE

2 Kì si iṣe ore diẹ li awọn alaigbede na ṣe fun wa: nitoriti nwọn daná, nwọn si gbà gbogbo wa si ọdọ nitori òjo igba na, ati itori otutù.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 28

Wo Iṣe Apo 28:2 ni o tọ