Iṣe Apo 4:16 YCE

16 Wipe, Kili a o ti ṣe awọn ọkunrin wọnyi? ti pe iṣẹ àmi ti o daju ti ọwọ́ wọn ṣe, o hàn gbangba fun gbogbo awọn ti ngbé Jerusalemu; awa kò si le sẹ́ ẹ.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 4

Wo Iṣe Apo 4:16 ni o tọ