Iṣe Apo 4:33 YCE

33 Agbara nla li awọn aposteli si fi njẹri ajinde Jesu Oluwa; ore-ọfẹ pipọ si wà lori gbogbo wọn.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 4

Wo Iṣe Apo 4:33 ni o tọ