Iṣe Apo 5:16 YCE

16 Ọ̀pọ enia si ko ara wọn jọ lati awọn ilu ti o yi Jerusalemu ka, nwọn nmu awọn abirùn wá, ati awọn ti ara kan fun ẹmi aimọ́: a si ṣe dida ara olukuluku wọn.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 5

Wo Iṣe Apo 5:16 ni o tọ