Iṣe Apo 5:17 YCE

17 Ṣugbọn olori alufa dide, ti on ti gbogbo awọn ti nwọn wà lọdọ rẹ̀ (ti iṣe ẹya ti awọn Sadusi), nwọn si kún fun owu.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 5

Wo Iṣe Apo 5:17 ni o tọ