Iṣe Apo 5:34 YCE

34 Ṣugbọn ọkan ninu ajọ igbimọ, ti a npè ni Gamalieli, Farisi ati amofin, ti o ni iyìn gidigidi lọdọ gbogbo enia, o dide duro, o ni ki a mu awọn aposteli bì sẹhin diẹ;

Ka pipe ipin Iṣe Apo 5

Wo Iṣe Apo 5:34 ni o tọ