55 Ṣugbọn on kún fun Ẹmí Mimọ́, o tẹjumọ́ ọrun, o si ri ogo Ọlọrun, ati Jesu nduro li ọwọ́ ọtún Ọlọrun.
Ka pipe ipin Iṣe Apo 7
Wo Iṣe Apo 7:55 ni o tọ