Iṣe Apo 9:40 YCE

40 Ṣugbọn Peteru ti gbogbo wọn sode, o si kunlẹ, o si gbadura; o si yipada si okú, o ni, Tabita, dide. O si là oju rẹ̀: nigbati o si ri Peteru, o dide joko.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 9

Wo Iṣe Apo 9:40 ni o tọ