1 Kíróníkà 10:2 BMY

2 Àwọn ará Fílístínì sí lépa Sáúlù gidigidi àti àwọn ọmọ Rẹ̀. Wọ́n sì pa àwọn ọmọ Rẹ̀. Jónátanì, Ábínádábù àti Málíkíṣúà.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 10

Wo 1 Kíróníkà 10:2 ni o tọ