1 Kíróníkà 12:21 BMY

21 Wọ́n sì ran Dáfídì lọwọ lórí ẹgbẹ́ ogun náà, nítorí gbogbo wọn ni akọni ènìyàn àwọn sì tún ni olórí nínú àwọn ọmọogun Rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 12

Wo 1 Kíróníkà 12:21 ni o tọ