1 Kíróníkà 13:8 BMY

8 Dáfídì àti gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ni wọ́n ṣe àjọyọ̀ pẹ̀lú gbogbo agbára wọn níwájú Ọlọ́run, pẹ̀lú orin àti pẹ̀lú ohun èlò orin olóhùn gooro, písátérù, tíńbálì, síńbálì àti ìpè.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 13

Wo 1 Kíróníkà 13:8 ni o tọ