1 Kíróníkà 13:9 BMY

9 Nígbà tí wọ́n dé sí ilẹ̀ pakà ti Kídónì, Úsà na ọwọ́ Rẹ̀ síta láti di àpótì ẹ̀rí Olúwa mú, nítorí màlúù kọ̀ṣẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 13

Wo 1 Kíróníkà 13:9 ni o tọ