16 Bẹ́ẹ̀ ni Dáfídì ṣe ohun tí Ọlọ́run ti pa láṣẹ fún wọn, wọ́n sì kọ lu àwọn ọmọ ogun Fílístínì láti gbogbo ọ̀nà Gíbíónì lọ sí Géṣérì.
Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 14
Wo 1 Kíróníkà 14:16 ni o tọ