1 Kíróníkà 15:16 BMY

16 Dáfídì sọ fún àwọn olórí àwọn Léfì láti yan àwọn arákùnrin wọn gẹ́gẹ́ bí akọrin láti kọ orin ayọ̀, pẹ̀lú àwọn ohun-èlò orin pisalitérì, dùùrù, àti Ṣíḿbálì.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 15

Wo 1 Kíróníkà 15:16 ni o tọ