1 Kíróníkà 15:17 BMY

17 Bẹ́ẹ̀ ni àwọn Léfì yan Hámánì ọmọ Jóẹ́lì; àti nínú àwọn arákùnrin Rẹ̀, Ásáfù ọmọ Bérékíà, àti nínú àwọn ọmọ Mérárì arákùnrin wọn, Étanì ọmọ Kúṣáíà;

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 15

Wo 1 Kíróníkà 15:17 ni o tọ