29 Bí àpótí ẹ̀rí májẹ̀mú Olúwa ti ń wọ ìlú ńlá Dáfídì, Míkálì ọmọbìnrin Ṣọ́ọ̀lù ń wò láti ojú fèrèsé nígbà tí ó sì rí ọba Dáfídì ń jó, ó sì ń ṣe àjọyọ̀, ó sì kẹ́gàn Rẹ̀ ní ọkàn Rẹ̀.
Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 15
Wo 1 Kíróníkà 15:29 ni o tọ