1 Kíróníkà 16:3 BMY

3 Nígbà náà ó fún olúkúlùkù ọkùnrin àti obìnrin ọmọ Ísírẹ́lí ní ìṣù àkàrà kan, àkàrà dídùn ti àkókò kan àti àkàrà dídùn ti èṣo àjàrà kan.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 16

Wo 1 Kíróníkà 16:3 ni o tọ