1 Kíróníkà 2:17 BMY

17 Ábígáílì ni ìyá Ámásà, ẹni tí baba Rẹ̀ sì jẹ́ Jétérì ará Íṣímáẹ́lì.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 2

Wo 1 Kíróníkà 2:17 ni o tọ