35 Ṣẹ́sánì sì fi ọmọ obìnrin Rẹ̀ ní aya fún ìránṣẹ́ Rẹ̀ Járíhà, ó sì bí ọmọ fún tí orúkọ Rẹ̀ jẹ́ Átaì.
36 Átaì sì jẹ́ baba fún Nátanì,Nátanì sì jẹ́ baba fún Ṣábádì,
37 Ṣábádì ni baba Éfúlálì,Éfúlálì jẹ́ baba Óbédì,
38 Óbédì sì ni baba Jéhù,Jéhù ni baba Ásáríyà,
39 Ásáríyà sì ni baba Hélésì,Hélésì ni baba Éléáṣáì,
40 Éléáṣáì ni baba Ṣísámálì,Ṣísámálì ni baba Ṣálúmù,
41 Ṣálúmù sì ni baba Élísámà.