39 Ásáríyà sì ni baba Hélésì,Hélésì ni baba Éléáṣáì,
40 Éléáṣáì ni baba Ṣísámálì,Ṣísámálì ni baba Ṣálúmù,
41 Ṣálúmù sì ni baba Élísámà.
42 Àwọn ọmọ Kálébù arákùnrin Jérámélì:Méṣà àkọ́bí Rẹ̀, ẹni tí ó jẹ́ baba fún Ṣífì àti àwọn ọmọ Rẹ̀ Méréṣà, ẹni tí ó jẹ́ baba fún Hébúrónì.
43 Àwọn ọmọ Hébúrónì:Kórà, Tápúà, Rékémù, àti Ṣémà.
44 Ṣémà ni baba Ráhámú Ráhámù sì jẹ́ baba fún Jóríkéámù. Rékémù sì ni baba Ṣémáì.
45 Àwọn ọmọ Ṣémáì ni Máónì, Máónì sì ni baba Bétí-Ṣúri.