1 Kíróníkà 2:42 BMY

42 Àwọn ọmọ Kálébù arákùnrin Jérámélì:Méṣà àkọ́bí Rẹ̀, ẹni tí ó jẹ́ baba fún Ṣífì àti àwọn ọmọ Rẹ̀ Méréṣà, ẹni tí ó jẹ́ baba fún Hébúrónì.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 2

Wo 1 Kíróníkà 2:42 ni o tọ