41 Ṣálúmù sì ni baba Élísámà.
42 Àwọn ọmọ Kálébù arákùnrin Jérámélì:Méṣà àkọ́bí Rẹ̀, ẹni tí ó jẹ́ baba fún Ṣífì àti àwọn ọmọ Rẹ̀ Méréṣà, ẹni tí ó jẹ́ baba fún Hébúrónì.
43 Àwọn ọmọ Hébúrónì:Kórà, Tápúà, Rékémù, àti Ṣémà.
44 Ṣémà ni baba Ráhámú Ráhámù sì jẹ́ baba fún Jóríkéámù. Rékémù sì ni baba Ṣémáì.
45 Àwọn ọmọ Ṣémáì ni Máónì, Máónì sì ni baba Bétí-Ṣúri.
46 Éfà Obìnrin Kélẹ́bù sì ni ìyá Hárà nì, Mósà àti Gásésì, Háránì sì ni baba Gásésì.
47 Àwọn ọmọ Jádáì:Régémù, Jótamù, Gésánì, Pétélì, Éfà àti Ṣáfù.