7 Àwọn ọmọ Kárímì:Ákárì, ẹni tí ó mú ìyọnu wá sórí Ísírẹ́lì nípa ẹ̀ṣẹ̀ ìfibú lórí mímú ohun ìyàsọ́tọ̀.
8 Àwọn ọmọ Étanì:Áṣáríyà
9 Àwọn ọmọ tí a bí fún Hésírónì ni:Jéráhímélì, Rámù àti Kélẹ́bù.
10 Rámù sì ni babaÁmínádábù, àti Ámínádábù baba Náṣónì olórí àwọn ènìyàn Júdà.
11 Náṣónì sì ni baba Sálímà, Sálímà ni baba Bóásì,
12 Bóásì baba Óbédì àti Óbédì baba Jésè.
13 Jésè sì ni BabaÉlíábù àkọ́bí Rẹ̀; ọmọ ẹlẹ́ẹ̀kẹjì sì ni Ábínádábù, ẹlẹ́ẹ̀kẹta ni Ṣíméà,