1 Kíróníkà 20:3 BMY

3 Ó sì kó gbogbo àwọn ènìyàn tí ó wà ní ibẹ̀ jáde, ó sì fi iṣẹ́ lé wọn lọ́wọ́ láti ṣíṣẹ́ pẹ̀lú ayùn àti ìtulẹ̀ onírin àti àáké. Dáfídì ṣe eléyìí sí gbogbo àwọn ará ìlú Ámónì. Nígbà náà, Dáfídì àti gbogbo àwọn ọmọ ogun Rẹ̀ padà sí Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 20

Wo 1 Kíróníkà 20:3 ni o tọ