1 Kíróníkà 23:9 BMY

9 Àwọn ọmọ Ṣímè:Ṣélómótì, Hásíélì àti Háránì mẹ́ta ní gbogbo wọn.Àwọn wọ̀nyí sì ni olórí àwọn ìdílé Ládánì.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 23

Wo 1 Kíróníkà 23:9 ni o tọ