1 Kíróníkà 25:5 BMY

5 Gbogbo àwọn wọ̀nyí sì ni ọmọ Hémánì àti wòlíì ọba. Wọ́n sì fi wọ́n fún nípa ìlérí Ọlọ́run láti máa gbé ìwo sókè. Ọlọ́run sì fún Hémánì ní ọmọkùnrin mẹ́rìnlá àti àwọn ọmọbìnrin mẹ́ta.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 25

Wo 1 Kíróníkà 25:5 ni o tọ