1 Kíróníkà 25:6 BMY

6 Gbogbo àwọn ọkùnrin yìí ni wọ́n wà lábẹ́ ìbojútó àwọn bàba wọn fún ohun èlò orin ilé Olúwa, pẹ̀lú Kínbálì, Písálítérì àti dùùrù, fún Ìsìn ilé Olúwa. Ásáfù, Jédútúnì, ọba.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 25

Wo 1 Kíróníkà 25:6 ni o tọ